ORÍKÍ ESÙ
Esú ota orisá
Osetura l'oruko baba mo o
alagogo ijà lóruko iyá npe e
esú odàrà omokunrin idolofin
o le sonso s'ori ese elese
ko je ko si je ki eni nje gbe e mi
a ki i l'owo lai mu t'esù kuro
a ki i l'ayo lai mu t'esù kuro
asotun sosi lai ni'tiju
esù apata somo olomo l'enu
o fi okuta dipo iyo
logemo orun a nla kalu
paapa warà a tuka mase i sa
esù ma se mi
omo elomiran ni ki o se.
Esú ota orisá
Osetura l'oruko baba mo o
alagogo ijà lóruko iyá npe e
esú odàrà omokunrin idolofin
o le sonso s'ori ese elese
ko je ko si je ki eni nje gbe e mi
a ki i l'owo lai mu t'esù kuro
a ki i l'ayo lai mu t'esù kuro
asotun sosi lai ni'tiju
esù apata somo olomo l'enu
o fi okuta dipo iyo
logemo orun a nla kalu
paapa warà a tuka mase i sa
esù ma se mi
omo elomiran ni ki o se.
boa noite motumba ,gostaria de saber quando tera toque .obrigado .
ResponderExcluir